[Gospel]: Iyabo Idowu – Ogo

Iyabo Idowu - Ogo
Iyabo Idowu – Ogo

Iyabo Idowu the most Nigerian veteran gospel minister released another hot inspirational song which she title “Ogo” (Glory).


With the fantastic song “Ogo” (Glory), Iyabo Idowu, a remarkably gifted Nigerian female gospel music superstar and songwriter, makes her debut.


Iyabo Idowu – Ogo lyrics.

Ooo ogo ooo ogo

Ologo nla ooo
Ologo aji mo roro
Oba kiki imole o
Oba ogo

(Tongues)

Oba o
Oba mi erujeje

Kos’eni le s’akawe ogo re b’oti tobi to
Kos’eni le s’akawe ogo re b’oti tobi to
Ogo ninu ogo
Ola t’ojola lo
Kiki imole kiki wura
Lofi dade
Ogo ninu ogo
Ola t’ojola lo
Kiki imole kiki ola nla o
Lofi dade

Alade mimo ogo t’obori ogo alade wura
Osumare ta yi’te re ka o
Aso igunwa re ogo ni
Ogo re kari aye
O kari awon orun
Otan’mole sinu omi
Gbogbo iseda n s’afihan ogo re
Ofurufu n fi’se owo re han
Orun osupa awon irawo
Oju orun won nfi titobi
Ogo re han
Iwo to ran afefe nise ooo
Ogun iji lesin
Riru okun riro ojo nsoro
Ogo re o ologo didan
Ogo re ole ku
Kole ti kole dibaje ooo
Ologo pipe

Ogo ninu ogo
Ola t’ojola lo
Kiki imole kiki wura
Lofi dade
Mose ri akehinsi ogo re
Oju mose ran bi orun
Kiki imole kiki ola nla o
Lofi dade

Kos’eni le s’akawe ogo re b’oti tobi to
Kos’eni le s’akawe ogo re b’oti tobi to
Ogo ninu ogo
Ola t’ojola lo
Kiki imole kiki wura
Lofi dade
Ogo ninu ogo
Ola t’ojola lo
Kiki imole kiki ola nla o
Lofi dade

Ooo ogo ooo ogo

Oba mi ooo
Oba to mo’ye awon irawo
Atofarati bi oke olori ogun
Iwo l’asiwaju Ogun l’alo o
Akehin Ogun l’abo

(Tongues)

Iwo l’oran afefe n’ise ooo
Erujeje ti’n mi’gbo kijikiji

(Tongues)

Oba mi eru t’oun gbe eru mi


Download and listen to Iyabo Idowu – Ogo.


Be the first to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published.